Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Tanzania

  • Ngibao village, nítòsí Arusha, Tanzania​—Wọ́n ń fi ìwé pẹlẹbẹ Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé lọ àwọn ẹ̀yà Masai

Ìsọfúnni Ṣókí—Tanzania

  • 67,438,000—Iye àwọn èèyàn
  • 20,846—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 417—Iye àwọn ìjọ
  • 3,392—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún