Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Sierra Leone

  • Freetown, Sierra Leone​—Wọ́n ń fi ìwé Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé lọni ní èdè Themne

  • Freetown Peninsula, Sierra Leone​—Wọ́n ń pe aládùúgbò kan wá sí ìpàdé ní Gbọ̀ngàn Ìjọba

  • Freetown, Sierra Leone​—Wọ́n ń fi ìwé Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé lọni ní èdè Themne

  • Freetown Peninsula, Sierra Leone​—Wọ́n ń pe aládùúgbò kan wá sí ìpàdé ní Gbọ̀ngàn Ìjọba

Ìsọfúnni Ṣókí—Sierra Leone

  • 8,472,000—Iye àwọn èèyàn
  • 2,564—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 42—Iye àwọn ìjọ
  • 3,621—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

O Ri I Pe Ife Lo Mu Ki Nnkan Wa Letoleto Nile Ijeun Naa

To ba je pe láti awon odun 1990 si 1999 tabi leyin igba naa lo to bere si i lo si apejo agbegbe awa Elerii Jehofa, a wu e lori láti ko nipa awon ohun ta a maa n se lawon apejo ta a ti se ni opo odun seyin.