Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Finland

  • Turku, Finland​—Wọ́n ń sọ nípa ohun tó wà nínú Bíbélì

Ìsọfúnni Ṣókí—Finland

  • 5,564,000—Iye àwọn èèyàn
  • 18,186—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 272—Iye àwọn ìjọ
  • 307—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Àkànṣe Ìwàásù Yọrí sí Rere ní Lapland

Kà nípa bí àwọn ọmọ ìbílẹ̀ Lapland ṣe tẹ́wọ́ gba ohun táwọn Ẹlẹ́rìí sapá lọ́nà tó ṣàrà ọ̀tọ̀ láti ṣe kí wọ́n lè ràn wọ́n lọ́wọ́.

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

A Fi Àádọ́ta Ọdún Ṣe Iṣẹ́ Ìsìn Ní Ilẹ̀ Olótùútù

Ka ìtan ìgbésí ayé Aili àti Annikki Mattila tí wọ́n kọ́ láti gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà nígbà tí wọ́n ń ṣe iṣẹ́ aṣáájù-ọ̀nà ní àríwá Finland.