Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Solomon Islands

  • Honiara, Solomon Islands​—Wọ́n ń sọ ohun tó wà nínú Bíbélì ní èdè Solomon Islands Pidgin

Ìsọfúnni Ṣókí—Solomon Islands

  • 738,000—Iye àwọn èèyàn
  • 1,907—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 50—Iye àwọn ìjọ
  • 430—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún