Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Serbia

  • Stara Pazova, Serbia​—Wọ́n ń fi àṣàrò kúkurú Ǹjẹ́ Àwọn Òkú Lè Jíǹde? lọni

Ìsọfúnni Ṣókí—Serbia

  • 6,641,000—Iye àwọn èèyàn
  • 3,733—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 60—Iye àwọn ìjọ
  • 1,800—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún