Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Madagascar

  • Antsirabe, Madagascar​—Wọ́n ń fi Ilé Ìṣọ́ lọ ẹni tó ń wa kẹ̀kẹ́

Ìsọfúnni Ṣókí—Madagascar

  • 29,443,000—Iye àwọn èèyàn
  • 40,035—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 841—Iye àwọn ìjọ
  • 763—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú​—Ní Madagásíkà

Ẹ jẹ́ ká mọ díẹ̀ lára àwọn akéde tó ṣí lọ sórílẹ̀-èdè Madagásíkà kí wọ́n lè wàásù ìhìn rere jákèjádò orílẹ̀-èdè yìí.