Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Paraguay

  • Nueva Durango Colony, Canindeyú, Paraguay​—Wọ́n ń fún obìnrin kan tó jẹ́ Mennonite ní ìwé pẹlẹbẹ Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé

Ìsọfúnni Ṣókí—Paraguay

  • 7,391,000—Iye àwọn èèyàn
  • 11,042—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 186—Iye àwọn ìjọ
  • 676—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún