Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Papua New Guinea

  • Port Moresby, Papua New Guinea​—Àwọn Ẹlẹ́rìí ń ka Bíbélì fún ẹnì kan ní èdè Tok Pisin

Ìsọfúnni Ṣókí—Papua New Guinea

  • 9,466,000—Iye àwọn èèyàn
  • 5,692—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 89—Iye àwọn ìjọ
  • 1,999—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA

Ọkọ̀ Ojú Omi Lightbearer Tan Ìmọ́lẹ̀ Òtítọ́ Dé Ilẹ̀ Éṣíà

Láìka àtakò sí, àwọn kéréje tó wà nínú ọkọ̀ ojú omi Lightbearer fi ìgboyà fún irúgbìn Ìjọba Ọlọ́run ní ọ̀pọ̀ ilẹ̀ tó láwọn èrò tó pọ̀ gan-an tí wọ́n ń gbé ibẹ̀.