Ìsọfúnni Ṣókí—Peru
- 33,966,000—Iye àwọn èèyàn
- 133,366—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 1,551—Iye àwọn ìjọ
- 261—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
IṢẸ́ ÌTẸ̀WÉ
Wọ́n Ń Gbọ́ Ìhìn Rere ní Agbègbè Andes
Àwọn tó ń sọ èdè Quechua ní orílẹ̀-èdè Peru túbọ̀ sún mọ́ Jèhófà bí wọ́n ṣe ń ka àwọn ìwé wa àti Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun lédè ìbílẹ̀ wọn.