Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Panama

  • Guna Yala, Panama​—Àwọn Ẹlẹ́rìí ń wàásù fún apẹja kan ní èdè ìbílẹ̀ rẹ̀, ìyẹn Guna (tí wọ́n ń pè ní Kuna tẹ́lẹ̀) ní erékùṣù Nurdub

Ìsọfúnni Ṣókí—Panama

  • 4,511,000—Iye àwọn èèyàn
  • 18,525—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 310—Iye àwọn ìjọ
  • 247—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún