Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Netherlands

Ìsọfúnni Ṣókí—Netherlands

  • 17,878,000—Iye àwọn èèyàn
  • 29,584—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 346—Iye àwọn ìjọ
  • 612—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

A Ṣe Tán Láti Sin Jèhófà Níbikíbi Tó Bá Fẹ́

Kà nípa bí tọkọtaya kan tó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Netherlands ṣe gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà pátápátá, láìka ìṣòro tí wọ́n dojú kọ àti bí ipò wọn ṣe ń yí pa dà sí.