Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Nicaragua

  • Las Pilas, Nicaragua​—Wọ́n ń kọ́ni látinú Bíbélì

Ìsọfúnni Ṣókí—Nicaragua

  • 6,855,000—Iye àwọn èèyàn
  • 28,843—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 466—Iye àwọn ìjọ
  • 240—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÍRÍ

Àkúnya Omi Mú Kí Wọ́n Gbọ́ Ìwàásù

Lẹ́yìn tí omi ya wọ àwọn abúlé kan ní Nicaragua, àwọn ará abúlé yẹn rí ìrànlọ́wọ́ gbà látọ̀dọ̀ àwọn tí wọn ò mọ̀ rí.