Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Nigeria

  • Idanre, Nigeria​—Wọ́n ń fún ẹnì kan ní ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́

Ìsọfúnni Ṣókí—Nigeria

  • 222,182,000—Iye àwọn èèyàn
  • 400,375—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 6,071—Iye àwọn ìjọ
  • 589—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ

Àwọn Ará Ń Gbádùn Tẹlifíṣọ̀n JW Láwọn Ibi Tí Ò Ti Sí Íńtánẹ́ẹ̀tì

Báwo làwọn ará ní Áfíríkà ṣe ń wo ètò tẹlifíṣọ̀n JW láìlo íńtánẹ́ẹ̀tì?

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Àpẹẹrẹ Àwọn Ẹni Tẹ̀mí Mú Kí N Fayé Mi Sin Jèhófà

Ka ìtàn ìgbésí ayé Woodworth Mills, kó o sì rí bó ṣe fayé rẹ̀ sin Jèhófà fún nǹkan bí ọgọ́rin (80) ọdún.