Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

New Caledonia

  • Anse Vata Beach, Nouméa, New Caledonia—Wọ́n ń ka Bíbélì

Ìsọfúnni Ṣókí—New Caledonia

  • 271,000—Iye àwọn èèyàn
  • 2,693—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 34—Iye àwọn ìjọ
  • 103—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣètò Ìrànwọ́ fún Àwọn Tí Ìjì Cyclone Pam Ṣe Lọ́ṣẹ́

Àwọn Ẹlẹ́rìí ń pèsè ìrànwọ́ fún àwọn tí ìjì Tropical Cyclone Pam ṣe lọ́ṣẹ́ wọ́n sì ń fi Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tù wọ́n nínú.