Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Namibia

  • Kunene region, Namibia​—Wọ́n ń fi ìwé pẹlẹbẹ Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé lédè Herero wàásù fún àwọn Himba

Ìsọfúnni Ṣókí—Namibia

  • 2,680,000—Iye àwọn èèyàn
  • 2,711—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 47—Iye àwọn ìjọ
  • 1,030—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún