Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Malawi

Ìsọfúnni Ṣókí—Malawi

  • 20,728,000—Iye àwọn èèyàn
  • 109,108—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 1,882—Iye àwọn ìjọ
  • 211—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Mo Jẹ́ Kí Jèhófà Tọ́ Mi Sọ́nà

Ìtàn Ìgbésí Ayé: Keith Eaton

BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ

Àpéjọ Agbègbè Lórí Tẹlifíṣọ̀n àti Rédíò

A gbé àpéjọ agbègbè 2020 sórí ìkànnì, àmọ́ ọ̀pọ̀ ní Màláwì àti Mòsáńbíìkì ò ní Íńtánẹ́ẹ̀tì. Báwo wá ni wọ́n ṣe wo àpéjọ náà?

BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ

Àwọn Ará Ń Gbádùn Tẹlifíṣọ̀n JW Láwọn Ibi Tí Ò Ti Sí Íńtánẹ́ẹ̀tì

Báwo làwọn ará ní Áfíríkà ṣe ń wo ètò tẹlifíṣọ̀n JW láìlo íńtánẹ́ẹ̀tì?

ÌRÒYÌN

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kọ Lẹ́tà Nítorí Àwọn Ará Wa ní Rọ́ṣíà​—Láti Màláwì

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Màláwì sọ bó ṣe rí lára wọn nígbà tí wọ́n kọ lẹ́tà sí ìjọba ilẹ̀ Rọ́ṣíà torí àwọn ará wa ní Rọ́ṣíà.

ÌRÒYÌN

Àwọn Ọmọ Ẹlẹ́rìí Jèhófà Méjì tí Àwọn Aláṣẹ Lé Kúrò Níléèwé Lórí Ọ̀rọ̀ Ẹ̀rí Ọkàn Ti Pa Dà Síléèwé

Torí pé àwọn ọmọ náà kọ̀ láti kọ orin orílẹ̀-èdè ni wọ́n ṣe lé wọn kúrò níléèwé. Àmọ́ àwọn aláṣẹ iléèwé ti ní kí wọ́n pa dà síléèwé báyìí.