Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Malta

  • Birgu, Malta​—Wọ́n ń fi àṣàrò kúkúrú Ibo La Ti Lè Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì Nípa Ìgbésí Ayé? lọni

Ìsọfúnni Ṣókí—Malta

  • 542,000—Iye àwọn èèyàn
  • 877—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 11—Iye àwọn ìjọ
  • 643—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún