Ìsọfúnni Ṣókí—Mongolia
- 3,423,000—Iye àwọn èèyàn
- 432—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 8—Iye àwọn ìjọ
- 8,431—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ÌRÒYÌN
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ti Lómìnira Ẹ̀sìn ní Mòǹgólíà: Ìjọba Pa Dà Forúkọ Ẹ̀sìn Wọn Sílẹ̀ Lábẹ́ Òfin
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní olú-ìlú orílẹ̀-èdè Mòǹgólíà gba ìwé ẹ̀rí kan látọ̀dọ̀ Àjọ Tó Ń Rí sí Ọ̀rọ̀ Ìlú, pé ìjọba ti pa dà forúkọ ẹ̀sìn wọn sílẹ̀ lábẹ́ òfin.