Ìsọfúnni Ṣókí—Moldova
- 2,978,000—Iye àwọn èèyàn
- 17,979—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 195—Iye àwọn ìjọ
- 167—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ILÉ ÌṢỌ́
Tálákà Ni Wá àmọ́ À Ń Fi Ayọ̀ Sin Ọlọ́run
Alexander Ursu rí i pé kò sẹ́ni tó lè dá ìjọsìn Ọlọ́run dúró, kódà ìjọba Soviet Union àtijọ́ kò lè dá a dúró. Ka ìtàn alárinrin kan nípa ìtàn ìgbésí ayé ẹnì yìí.