Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Latvia

  • Riga, Latvia—Wọ́n ń fi bí èèyàn ṣe lè lo ìkànnì jw.org han ẹnì kan

Ìsọfúnni Ṣókí—Latvia

  • 1,883,000—Iye àwọn èèyàn
  • 2,135—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 29—Iye àwọn ìjọ
  • 898—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́

“Ìlérí Párádísè Yí Ìgbésí Ayé Mi Pa Dà”

Ọ̀gbẹ́ni kan tó ń jẹ Ivars Vigulis gbádùn òkìkí àti ògo tó wà nínú fifi alùpùpù díje. Báwo ni ẹ̀kọ́ Bíbélì ṣe tún ayé rẹ̀ ṣe?