Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Lesotho

  • Abúlé Setibing, Lesotho—Wọ́n ń fi èdè Sesotho sọ ohun tó wà nínú Bíbélì fún ẹnì kan

  • Bokong, Lesotho​—Wọ́n ń fi ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ lọni

  • Abúlé Setibing, Lesotho—Wọ́n ń fi èdè Sesotho sọ ohun tó wà nínú Bíbélì fún ẹnì kan

  • Bokong, Lesotho​—Wọ́n ń fi ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ lọni

Ìsọfúnni Ṣókí—Lesotho

  • 2,192,000—Iye àwọn èèyàn
  • 4,222—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 81—Iye àwọn ìjọ
  • 566—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún