Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Liberia

  • Nítòsí Monrovia, Liberia​—Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń fún ẹnì kan ní ìwé àṣàrò kúkúrú Igbesi-aye ninu Aye Titun alalaafia kan

Ìsọfúnni Ṣókí—Liberia

  • 5,432,000—Iye àwọn èèyàn
  • 7,922—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 146—Iye àwọn ìjọ
  • 745—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún