Ìsọfúnni Ṣókí—Kazakhstan
- 19,899,000—Iye àwọn èèyàn
- 17,287—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 229—Iye àwọn ìjọ
- 1,164—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
JÍ!
Ẹ Já Ká Lọ sí Orílẹ̀-Èdè Kazakhstan
Láyé àtijọ́, darandaran ni àwọn èèyàn ilẹ̀ Kazakhstan inú ilé kan tó rí roboto ni wọ́n sábà máa ń gbé. Báwo wa ni ìgbé ayé wọn nísìnyí ṣe jẹ́ ká mọ̀ nípa àṣà ìbílẹ̀ wọn?