Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Kyrgyzstan

  • Bishkek, Kyrgyzstan​—Wọ́n ń fi fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? han ẹnì kan ní èdè Kirghiz

Ìsọfúnni Ṣókí—Kyrgyzstan

  • 7,038,000—Iye àwọn èèyàn
  • 5,167—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 86—Iye àwọn ìjọ
  • 1,387—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Ohun Gbogbo Ṣeé Ṣe Lọ́dọ̀ Jèhófà

Ọ̀rọ̀ tí arábìnrin kan sọ nínú bọ́ọ̀sì lórílẹ̀-èdè Kyrgyzstan ló yí ìgbésí ayé àwọn tọkọtaya kan padà.

JÍ!

Ìbẹ̀wò sí Orílẹ̀-èdè Kyrgyzstan

Àwọn èèyàn ìlú Kyrgyzstan kóni mọ́ra wọ́n sì ń bọ̀wọ̀ fúnni. Àwọn àṣà wo ní wọ́n máa ń dá nínú ọ̀pọ̀ ìdílé níbẹ̀?