Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Japan

  • Tokyo, Japan​—Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń fi ìkànnì jw.org wàásù fún obìnrin adití kan

  • Kamaishi, Japan​—Lẹ́yìn ìmìtìtì ilẹ̀ àti àkúnya omi tó wáyé lọ́dún 2011, àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń bá àwọn tó yè é sọ̀rọ̀ ní ibi tí wọ́n ń gbé fúngbà díẹ̀

Ìsọfúnni Ṣókí—Japan

  • 124,752,000—Iye àwọn èèyàn
  • 214,457—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 2,888—Iye àwọn ìjọ
  • 583—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún