Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Jamaica

  • Woodford, St. Andrew, Jamaica​—Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń fún ẹnì kan ní ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ àti Jí!

Ìsọfúnni Ṣókí—Jamaica

  • 2,996,000—Iye àwọn èèyàn
  • 10,988—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 152—Iye àwọn ìjọ
  • 279—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún