Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Israel

  • Tel Aviv, Israel​—Wọ́n ń fi èdè Russian wàásù ní etíkun

Ìsọfúnni Ṣókí—Israel

  • 9,888,000—Iye àwọn èèyàn
  • 2,129—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 32—Iye àwọn ìjọ
  • 4,731—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

A Túbọ̀ Ń Wàásù Níbi Térò Pọ̀ sí Lórilè-Èdè Israel Bí Ẹgḅẹẹgbẹ̀rún Èèyàn Ṣe Ń Ṣèbẹ̀wò Sílùú Tel Aviv

Ní May 2019, àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà lórílẹ̀-èdè Israel sapá gan-an láti túbọ̀ wàásù láwọn ibi térò pọ̀ sí ní ìlú Tel Aviv.