Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Indonesia

  • Bali, Indonesia​—Wọ́n ń kọ́ ẹnì kan tó ń ṣiṣẹ́ ní oko ìrẹsì lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní tòsí ìlú Ubud

Ìsọfúnni Ṣókí—Indonesia

  • 281,844,000—Iye àwọn èèyàn
  • 31,023—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 491—Iye àwọn ìjọ
  • 9,275—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2016

Indonéṣíà

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lo ìgboyà wọ́n sì di ìgbàgbọ́ wọn mú láìka rògbòdìyàn ìṣèlú, ìjà ẹ̀sìn àti báwọn ẹlẹ́sìn ṣe fa ìfòfindè iṣẹ́ ìwàásù wọn fún ọdún 25.

ÌRÒYÌN

Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàjáwìrì Kárí Ayé: Bá A Ṣe Ń Ran Àwọn Ará Wa Lọ́wọ́ Tí Àjálù Àtàwọn Pàjáwìrì Míì Bá Ṣẹlẹ̀

Ìgbìmọ̀ Olùdarí á máa fún àwọn ará kárí ayé ní ìtọ́ni tó bọ́ sásìkò nígbà tí àjálù bá ṣẹlẹ̀.

LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA

Ọkọ̀ Ojú Omi Lightbearer Tan Ìmọ́lẹ̀ Òtítọ́ Dé Ilẹ̀ Éṣíà

Láìka àtakò sí, àwọn kéréje tó wà nínú ọkọ̀ ojú omi Lightbearer fi ìgboyà fún irúgbìn Ìjọba Ọlọ́run ní ọ̀pọ̀ ilẹ̀ tó láwọn èrò tó pọ̀ gan-an tí wọ́n ń gbé ibẹ̀.