Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Hungary

  • The Danube River, Budapest, Hungary—Wọ́n ń fún ẹnì kan ní ìwé tó dá lórí Bíbélì

Ìsọfúnni Ṣókí—Hungary

  • 9,597,000—Iye àwọn èèyàn
  • 21,332—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 283—Iye àwọn ìjọ
  • 453—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

Iléeṣẹ́ Holocaust Memorial Center Lórílẹ̀-èdè Hungary Ṣí Àmì Ẹ̀yẹ Kan Láti Fi Yẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tí Ìjọba Násì Pa Sí

Wọ́n ṣí àmì ẹ̀yẹ kan ní iléeṣẹ́ Holocaust Memorial Center nílùú Budapest láti fi rántí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà mẹ́rin tí wọ́n pa torí ẹ̀rí ọkàn ò gbà wọ́n láyè láti ṣiṣẹ́ ológun nígbà Ogun Àgbáyé Kejì.