Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Croatia

  • Zagreb, Croatia​—Ẹlẹ́rìí kan ń fún ẹnì kan ní ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ ní òpópónà Ilica

  • Rovinj, Croatia​—Wọ́n ń fi ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run! lọni

  • Rovinj, Croatia​—Wọ́n ń fi ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

  • Zagreb, Croatia​—Wọ́n ń fi ìwé àṣàrò kúkúrú Ibo La Ti Lè Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì Nípa Ìgbésí Ayé? lọni

  • Zagreb, Croatia​—Wọ́n ń sọ̀rọ̀ ìrètí tó wà nínú Bíbélì

  • Pula, Croatia​—Wọ́n ń fi àṣàrò kúkúrú, Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Ọ̀la? lọni nítòsí gbọ̀ngàn ìwòran àwọn ará Róòmù àtijọ́

Ìsọfúnni Ṣókí—Croatia

  • 4,038,000—Iye àwọn èèyàn
  • 4,687—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 57—Iye àwọn ìjọ
  • 870—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún