Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Hong Kong

  • Shau Kei Wan, Hong Kong—Wọ́n ń fún ẹnì kan ní ìwé ìroyìn Jí!

Ìsọfúnni Ṣókí—Hong Kong

  • 7,498,000—Iye àwọn èèyàn
  • 5,464—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 70—Iye àwọn ìjọ
  • 1,380—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́

Mo Rí Ohun Tó Sàn Ju Òkìkí

Mina Hung Godenzi di olókìkí lọ́sàn kan òru kan, àmọ́ ayé rẹ̀ kò rí bó ṣe rò.