Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Guyana

Ìsọfúnni Ṣókí—Guyana

  • 798,000—Iye àwọn èèyàn
  • 3,280—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 46—Iye àwọn ìjọ
  • 249—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÍRÍ

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú Lórílẹ̀-èdè Guyana

Ẹ̀kọ́ pàtàkì wo la rí kọ́ lára àwọn tó lọ sìn níbi tí wọ́n ti nílò àwọn oníwàásù púpọ̀ sí i? Tó bá wù ẹ́ láti lọ sìn nílẹ̀ òkèèrè, báwo làwọn ẹ̀kọ́ tó o kọ́ yìí ṣe lè mú kó o múra sílẹ̀ láti ṣe bẹ́ẹ̀?