Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Guam

  • Merizo Pier, Guam—Wọ́n ń fi ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run! lọni

Ìsọfúnni Ṣókí—Guam

  • 173,000—Iye àwọn èèyàn
  • 709—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 9—Iye àwọn ìjọ
  • 250—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Micronesia

Ó kéré tán ìpèníjà mẹ́ta làwọn tó ti òkèèrè wá sìn ní erékùṣù Pàsífí ìkì sábà máa ń ní. Àmọ́, kí ló ran àwọn àkéde yìí lọ́wọ́?