Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Guinea

  • Diecke, Guinea​—Wọ́n ń fún ẹnì kan ní ìwé tá a fi ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

Ìsọfúnni Ṣókí—Guinea

  • 14,239,000—Iye àwọn èèyàn
  • 1,217—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 27—Iye àwọn ìjọ
  • 12,403—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Jèhófà Dáàbò Bò Mí Torí Mo Gbẹ́kẹ̀ Lé E

Ìtàn Ìgbésí Ayé: Israel Itajobi.