Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Greenland

  • Oqaatsut, Greenland​—Wọ́n ń bá ìdílé kan tí wọ́n jẹ́ ọmọ ilẹ̀ yìí sọ̀rọ̀ látinú Bíbélì

Ìsọfúnni Ṣókí—Greenland

  • 57,000—Iye àwọn èèyàn
  • 119—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 5—Iye àwọn ìjọ
  • 500—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún