Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Ghana

  • Aburi, Ghana—Wọ́n ń wàásù nípa Ìjọba Ọlọ́run

Ìsọfúnni Ṣókí—Ghana

  • 33,063,000—Iye àwọn èèyàn
  • 153,657—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 2,484—Iye àwọn ìjọ
  • 220—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Gánà

Ìṣòro táwọn tó lọ sìn níbi tí àìní wà máa ń pọ̀. Àmọ́ èyí kì í tó nǹkan kan tá a bá fi wé àwọn ìbùkún tí wọ́n máa ń rí.