Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Georgia

  • Gurgeniani, Georgia​—Wọ́n ń fi ìwé náà, Kí Ló Wà Nínú Bíbélì? lọni

Ìsọfúnni Ṣókí—Georgia

  • 3,736,000—Iye àwọn èèyàn
  • 18,841—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 224—Iye àwọn ìjọ
  • 199—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

Àkànṣe Àpéjọ Àkọ́kọ́ Tó Wáyé Nílùú Tbilisi, ní Jọ́jíà

Àpéjọ yìí jẹ́ àkọ́kọ́ irú ẹ̀ ní Jọ́jíà, ọ̀pọ̀ àsọyé tó ń gbéni ró, tó sì dá lórí Bíbélì ni wọ́n gbọ́ níbẹ̀, àwọn ará fìfẹ́ gba àwọn ará wọn lálejò, wọ́n sì ṣàfihàn àṣà ìbílẹ̀ wọn àti ìtàn ilẹ̀ wọn.

ÌRÒYÌN

Orílẹ̀-èdè Jọ́jíà Gbà Pé Àwọn Jẹ̀bi Nílé Ẹjọ́ Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn Ti Ilẹ̀ Yúróòpù

Ilé Ẹjọ́ Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn Ti Ilẹ̀ Yúróòpù (ECHR) sọ ìpinnu wọn pé àwọ́n ti gbọ́ ẹ̀bẹ̀ orílẹ̀-èdè Jọ́jíà nípa àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà mẹ́wàá.

ÌRÒYÌN

Ilé Ẹjọ́ Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn ti Ilẹ̀ Yúróòpù Fọwọ́ sí I Pé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Lẹ́tọ̀ọ́ Láti Ṣe Ẹ̀sìn Wọn ní Jọ́jíà

Ẹjọ́ tí ilé ẹjọ́ ECHR dá lẹ́nu àìpẹ́ yìí jẹ́ káwọn Ẹlẹ́rìí lè pàdé pọ̀ láti jọ́sìn fàlàlà, kí wọ́n sì bá àwọn aládùúgbò wọn sọ ohun tí wọ́n gbà gbọ́ láìsí wàhálà.

ILÉ ÌṢỌ́

Ìṣura Kan Tó Fara Sin Láti Ọgọ́rọ̀ọ̀rún Ọdún

Wo bí wọ́n ṣe ṣàwárí Bíbélì tí àwọn èèyàn kà sí èyí tó tí ì pẹ́ jù lọ lédè Georgian