Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Britain

  • London, England​—Wọ́n ń bá àwọn tó ń sọdá afárá Westminster Bridge sọ̀rọ̀

Ìsọfúnni Ṣókí—Britain

  • 66,357,000—Iye àwọn èèyàn
  • 142,073—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 1,599—Iye àwọn ìjọ
  • 474—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÀWỌN IṢẸ́ ÌKỌ́LÉ

“Àwọn Obìnrin Láyè Tiwọn Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìkọ́lé”

Ó lè yà ẹ́ lẹ́nu tó o bá gbọ́ àwọn iṣẹ́ tí wọ́n mọ̀ ọ́n ṣe.

ÀWỌN IṢẸ́ ÌKỌ́LÉ

Wọn Ò Pa Ẹran Igbó Lára Nílùú Chelmsford

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ti bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ẹ̀ka ọ́fíìsì wọn tuntun sí tòsí ìlú Chelmsford. Kí ni wọ́n ń ṣe kí wọ́n má bàa pa ẹran igbó lára?