Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Spain

  • Barcelona, Spain—Àwọn èdè bíi Arabic, Catalan, Gẹ̀ẹ́sì, Faransé, Spanish àti Urdu làwọn Ẹlẹ́rìí fi ń wàásù níbí

  • Agaete, Canary Islands, Spain​—Wọ́n ń fi ìwé pẹlẹbẹ Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run! lọni

Ìsọfúnni Ṣókí—Spain

  • 48,197,000—Iye àwọn èèyàn
  • 122,061—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 1,397—Iye àwọn ìjọ
  • 397—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÍRÍ

Ilé Olódi Tí Wọ́n ti Dán Ìgbàgbọ́ Àwọn Èèyàn Jèhófà Wò

Ilé olódi kan wà lórílẹ̀-èdè Sípéènì tí wọ́n ti fi ọgọ́rọ̀ọ̀rún àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sẹ́wọ̀n torí pé ẹ̀rí ọkàn wọn ò jẹ́ kí wọ́n lè ṣiṣẹ́ ológun.

JÍ!

Ìbẹ̀wò sí Orílẹ̀-Èdè Sípéènì

Onírúurú nǹkan ló wà lórílẹ̀-èdè Sípéènì, látorí àwọn èèyàn títí dorí ilẹ̀ wọn. Irú oúnjẹ kan wà tí wọ́n ń ṣe lórílẹ̀-èdè Sípéènì àmọ́ tí kò sí lórílẹ̀-èdè mí ì lágbàáyé.

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Àwọn Obìnrin Ajẹ́jẹ̀ẹ́ Ìnìkàngbé Di Ìránṣẹ́ Jèhófà

Kí ló mú kí wọ́n kúrò ní ilé àwọn ajẹ́jẹ̀ẹ́ ìnìkàngbé, tí wọ́n sì fi ẹ̀sìn Kátólí ìkì sílẹ̀?