Ìsọfúnni Ṣókí—Germany
- 84,359,000—Iye àwọn èèyàn
- 174,907—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 2,002—Iye àwọn ìjọ
- 488—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ÌRÒYÌN
Ojúkò Àgọ́ Ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́ Kan Ṣàfihàn Bí Wọ́n Ṣe Pọ́n Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Lójú ní Jámánì
Ètò kan tí wọ́n ṣe láwọn ìlú ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní Jámánì ṣàfihàn bí ìjọba Násì àti ìjọba GDR ṣe pọ́n àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lójú nítorí ìgbàgbọ́ wọn.
LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA
Ohun Tó Dáa Jù Ni Wọ́n Fi Ránṣẹ́
Báwo làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe ran àwọn ará wọn ní Jámánì lọ́wọ́ gbàrà tí Ogun Àgbáyé Kejì parí?