Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Cape Verde

  • Mindelo, Cape Verde​—Wọ́n ń fi ìwé pẹlẹbẹ Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run! lọni

Ìsọfúnni Ṣókí—Cape Verde

  • 573,000—Iye àwọn èèyàn
  • 2,277—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 35—Iye àwọn ìjọ
  • 256—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún