Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Costa Rica

  • Zarcero, Costa Rica​—Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń bá darandaran kan jíròrò Bíbélì ní ẹ̀yìn odi ìlú

Ìsọfúnni Ṣókí—Costa Rica

  • 5,213,000—Iye àwọn èèyàn
  • 32,084—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 429—Iye àwọn ìjọ
  • 163—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún