Ìsọfúnni Ṣókí—Cameroon
- 28,608,000—Iye àwọn èèyàn
- 44,558—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 500—Iye àwọn ìjọ
- 665—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
Àwọn Iṣẹ́ Ìkọ́lé Tá A Ṣe Kí Àrùn Corona Tó Bẹ̀rẹ̀
A pinnu láti kọ́ tàbí ṣàtúnṣe sáwọn ibi ìjọsìn tó lé ní ẹgbẹ̀rún méjì àti ọgọ́rùn-ún méje (2,700) láàárín ọdún iṣẹ́ ìsìn 2020. Báwo ni àrùn Corona ṣe dí àwọn iṣẹ́ náà lọ́wọ́?