Ìsọfúnni Ṣókí—Congo, Republic of
- 5,941,000—Iye àwọn èèyàn
- 9,517—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 123—Iye àwọn ìjọ
- 661—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
BÁ A ṢE Ń RAN ARÁ ÌLÚ LỌ́WỌ́
Tí Àjálù Bá Ṣẹlẹ̀, Ìfẹ́ Máa Ń Mú Ká Ṣèrànwọ́
Onírúurú orílẹ̀-èdè làwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti máa ń ṣèrànwọ́ nígbà àjálù.