Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Central African Republic

Ìsọfúnni Ṣókí—Central African Republic

  • 5,119,000—Iye àwọn èèyàn
  • 2,932—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 64—Iye àwọn ìjọ
  • 1,791—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Orílẹ̀-Èdè Central African Republic Sá Kúrò Nílùú Nítorí Ogun Abẹ́lé

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà wà lára àwọn ẹgbẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́rùn-ún àwọn èèyàn tó sá kúrò lórílè-èdè Central African Republic lọ sí àwọn orílẹ̀-èdè tó wà láyìíká nítorí ìjà ẹ̀sìn àti ìjà kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà.

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Mo Pinnu Pé Mi Ò Ní Juwọ́ Sílẹ̀

Ka àwọn ìrírí tí Maxim Danyleyko ti ní ní gbogbo ọdún méjìdínláàádọ́rin [68] tó fi ṣe míṣọ́nnárì.