Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Belize

  • Corozal, Belize​—Wọ́n ń sọ ohun tó wà nínú Bíbélì fún ọkùnrin kan tó ń ṣiṣẹ́

Ìsọfúnni Ṣókí—Belize

  • 441,000—Iye àwọn èèyàn
  • 2,492—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 53—Iye àwọn ìjọ
  • 180—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún