Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Botswana

  • Sepupa, Botswana​—Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń wàásù fún apẹja kan létí odò Okavango

Ìsọfúnni Ṣókí—Botswana

  • 2,346,000—Iye àwọn èèyàn
  • 2,391—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 42—Iye àwọn ìjọ
  • 1,016—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Wọ́n Pàtẹ Ìṣúra Tó Ṣàrà Ọ̀tọ̀ ní Botswana

Fídíò bèbí tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà gbàfiyèsí àwọn ọmọdé. Ọ̀wọ́ àwọn fídíò yìí máa ń jẹ́ kéèyàn rí béèyàn ṣe lè máa tẹ̀ lé àwọn ìlànà Bíbélì.