Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

St. Barthélemy

Ìsọfúnni Ṣókí—St. Barthélemy

  • 11,000—Iye àwọn èèyàn
  • 40—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 1—Iye àwọn ìjọ
  • 297—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

Ohun Tó Ṣẹlẹ̀ Lẹ́yìn Ìjì Líle Hurricane Irma

Ìròyìn láti ẹ̀ka ọ́fíìsì wa ní in Barbados, Dominican Republic, France, àti Amẹ́ríkà.