Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Benin

  • Ìtòsí ìlú Boukoumbé, Benin​—Wọ́n ń fi ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run! lọni

Ìsọfúnni Ṣókí—Benin

  • 13,124,000—Iye àwọn èèyàn
  • 14,838—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 260—Iye àwọn ìjọ
  • 930—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Ìwọ̀ Oòrùn Áfíríkà

Kí lóhun tó mú kí àwọn kan fi ilẹ̀ Yúróòpù sílẹ̀ lọ sí ilẹ̀ Áfíríkà? Kí ló sì ti jẹ́ àbájáde ìgbésẹ̀ tí wọ́n gbé yìí?

ILÉ ÌṢỌ́

Ṣé Apá Mi Á Lè Ká Ohun Tí Mo Dáwọ́ Lé Yìí?

Kà nípa bí miṣọ́nnárì kan lórílẹ̀-èdè Benin ṣe kọ́ èdè àwọn adití kó lè ran àwọn adití lọ́wọ́ láti sún mọ́ Ọlọ́run.