Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Burundi

  • Muruta, Ìpínlẹ̀ Kayanza, Burundi​—Wọ́n ń fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ àgbẹ̀ kan tó ń sọ èdè Kirundi

Ìsọfúnni Ṣókí—Burundi

  • 12,999,000—Iye àwọn èèyàn
  • 18,129—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 374—Iye àwọn ìjọ
  • 749—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Jèhófà ‘Mú Kí Àwọn Ọ̀nà Mi Tọ́’